Rom 15:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki a le gbà mi lọwọ awọn alaigbọran ni Judea ati ki iṣẹ-iranṣẹ ti mo ni si Jerusalemu le jẹ itẹwọgbà lọdọ awọn enia mimọ́.

Rom 15

Rom 15:24-32