Rom 15:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si bẹ̀ nyin, ará, nitori Oluwa wa Jesu Kristi, ati nitori ifẹ Ẹmí, ki ẹnyin ki o ba mi lakaka ninu adura nyin si Ọlọrun fun mi;

Rom 15

Rom 15:20-33