Oni 9:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ifẹ wọn pẹlu, ati irira wọn, ati ilara wọn, o parun nisisiyi; bẹ̃ni nwọn kò si ni ipin mọ lailai ninu ohun gbogbo ti a nṣe labẹ õrùn.

Oni 9

Oni 9:5-9