Oni 9:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori alãye mọ̀ pe awọn o kú; ṣugbọn awọn okú kò mọ̀ ohun kan, bẹ̃ni nwọn kì ili ère mọ; nitori iranti wọn ti di igbagbe.

Oni 9

Oni 9:4-6