O. Sol 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Igi ọ̀pọtọ so eso titun, awọn àjara funni ni õrun daradara nipa itanná wọn. Dide, olufẹ mi, arẹwà mi kanna, ki o si jade kalọ.

O. Sol 2

O. Sol 2:8-17