O. Sol 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn itanna eweko farahàn lori ilẹ; akoko ikọrin awọn ẹiyẹ de, a si gbọ ohùn àdaba ni ilẹ wa.

O. Sol 2

O. Sol 2:4-17