O. Daf 136:11-13 Yorùbá Bibeli (YCE)

11. O si mu Israeli jade kuro lãrin wọn: nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai:

12. Pẹlu ọwọ agbara, ati apa ninà: nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai.

13. Fun ẹniti o pin Okun pupa ni ìya: nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai:

O. Daf 136