O. Daf 122:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. INU mi dùn nigbati nwọn wi fun mi pe, Ẹ jẹ ki a lọ si ile Oluwa.

2. Ẹsẹ wa yio duro ni ẹnu-bode rẹ, iwọ Jerusalemu.

3. Jerusalemu, iwọ ti a kọ́ bi ilu ti o fi ara mọra pọ̀ ṣọkan.

O. Daf 122