O. Daf 1:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si dabi igi ti a gbìn si eti ipa odò, ti nso eso rẹ̀ jade li akokò rẹ̀; ewe rẹ̀ kì yio si rẹ̀; ati ohunkohun ti o ṣe ni yio ma ṣe dede.

O. Daf 1

O. Daf 1:1-6