O. Daf 1:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn didùn-inu rẹ̀ wà li ofin Oluwa; ati ninu ofin rẹ̀ li o nṣe aṣaro li ọsan ati li oru.

O. Daf 1

O. Daf 1:1-3