Num 33:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

WỌNYI ni ìrin awọn ọmọ Israeli, ti o ti ilẹ Egipti jade wá pẹlu awọn ogun wọn, nipa ọwọ́ Mose ati Aaroni.

Num 33

Num 33:1-4