Num 23:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe lati ori apata wọnni ni mo ri i, ati lati òke wọnni ni mo wò o: kiyesi i, awọn enia yi yio dágbé, a ki yio si kà wọn kún awọn orilẹ-ède.

Num 23

Num 23:1-19