Num 23:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tali o le kà erupẹ Jakobu, ati iye idamẹrin Israeli? Jẹ ki emi ki o kú ikú olododo, ki igbẹhin mi ki o si dabi tirẹ̀!

Num 23

Num 23:4-12