Mak 6:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Iṣu akara melo li ẹnyin ni? ẹ lọ wò o. Nigbati nwọn si mọ̀, nwọn wipe, Marun, pẹlu ẹja meji.

Mak 6

Mak 6:34-42