Mak 6:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn o dahùn o si wi fun wọn pe, Ẹ fun wọn li onjẹ. Nwọn si wi fun u pe, Awa o ha lọ irà akara igba owo idẹ ki a si fifun wọn jẹ?

Mak 6

Mak 6:28-42