Mak 3:14-16 Yorùbá Bibeli (YCE)

14. O si yàn awọn mejila, ki nwọn ki o le mã gbé ọdọ rẹ̀, ati ki o le ma rán wọn lọ lati wasu,

15. Ati lati li agbara lati wò arunkarun san, ati lati lé awọn ẹmi èṣu jade:

16. Simoni ẹniti o si sọ apele rẹ̀ ni Peteru;

Mak 3