Mak 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si yàn awọn mejila, ki nwọn ki o le mã gbé ọdọ rẹ̀, ati ki o le ma rán wọn lọ lati wasu,

Mak 3

Mak 3:7-19