Mak 16:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si jade lọ, nwọn si nwasu nibigbogbo, Oluwa si mba wọn ṣiṣẹ, o si nfi idi ọ̀rọ na kalẹ, nipa àmi ti ntẹ̀le e. Amin.

Mak 16

Mak 16:10-20