Mak 16:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni nigbati Oluwa si ti ba wọn sọ̀rọ tan, a si gbà a lọ soke ọrun, o si joko li ọwọ́ ọtún Ọlọrun.

Mak 16

Mak 16:14-20