Mak 1:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o di aṣalẹ, ti õrun wọ̀, nwọn gbe gbogbo awọn alaìsan, ati awọn ti o li ẹmi i èṣu tọ̀ ọ wá.

Mak 1

Mak 1:22-33