Mak 1:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wá, o fà a lọwọ, o si gbé e dide; lojukanna ibà na si fi i silẹ, o si nṣe iranṣẹ fun wọn.

Mak 1

Mak 1:25-41