Luk 8:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn obinrin kan, ti a ti mu larada kuro lọwọ awọn ẹmi buburu, ati ninu ailera wọn, Maria ti a npè ni Magdalene, lara ẹniti ẹmi èṣu meje ti jade kuro,

Luk 8

Luk 8:1-9