Luk 8:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe lẹhinna, ti o nlà gbogbo ilu ati iletò lọ, o nwasu, o nrò ìhin ayọ̀ ijọba Ọlọrun: awọn mejila si mbẹ lọdọ rẹ̀.

Luk 8

Luk 8:1-8