Luk 11:49 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori eyi li ọgbọ́n Ọlọrun si ṣe wipe, emi ó rán awọn woli ati awọn aposteli si wọn, ninu wọn ni nwọn o si pa, ti nwọn o si ṣe inunibini si:

Luk 11

Luk 11:40-54