Luk 11:48 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ ẹnyin njẹ ẹlẹri, ẹ si ni inudidun si iṣe awọn baba nyin: nitori nwọn pa wọn, ẹnyin si kọ́le oju-õrì wọn.

Luk 11

Luk 11:42-54