Joṣ 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati pe ẹnyin o pa baba mi mọ́ lãye, ati iya mi, ati awọn arakunrin mi, ati awọn arabinrin mi, ati ohun gbogbo ti nwọn ní, ki ẹnyin si gbà ẹmi wa lọwọ ikú.

Joṣ 2

Joṣ 2:6-17