Joṣ 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nitorina, emi bẹ̀ nyin, ẹ fi OLUWA bura fun mi, bi mo ti ṣe nyin li ore, ẹnyin o ṣe ore pẹlu fun ile baba mi, ẹnyin o si fun mi li àmi otitọ:

Joṣ 2

Joṣ 2:8-16