Jer 52:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu ọba Babeli fọ Sedekiah li oju; o si fi ẹ̀wọn dè e, o si mu u lọ si Babeli, o si fi sinu tubu titi di ọjọ ikú rẹ̀.

Jer 52

Jer 52:4-17