Jer 49:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Damasku di alailera, o yi ara rẹ̀ pada lati sa, iwarìri si dì i mu: ẹ̀dun ati irora ti dì i mu, gẹgẹ bi obinrin ti nrọbi.

Jer 49

Jer 49:20-31