Jer 49:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si Damasku. Oju tì Hamati, ati Arpadi: nitori nwọn ti gbọ́ ìhin buburu: aiya ja wọn; idãmu wà lẹba okun; nwọn kò le ri isimi.

Jer 49

Jer 49:17-24