Jer 44:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nwọn kò gbọ́, bẹ̃ni nwọn kò tẹti wọn silẹ lati yipada kuro ninu ìwa-buburu wọn, ki nwọn ki o má sun turari fun ọlọrun miran.

Jer 44

Jer 44:1-12