Jer 44:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi si ran gbogbo awọn iranṣẹ mi, awọn woli si nyin, emi dide ni kutukutu, mo rán wọn, wipe, A! ẹ máṣe ohun irira yi ti emi korira.

Jer 44

Jer 44:1-5