Jer 41:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Iṣmaeli, ọmọ Netaniah, bọ́ lọwọ Johanani pẹlu ọkunrin mẹjọ, o si lọ sọdọ awọn ọmọ Ammoni.

Jer 41

Jer 41:10-18