Jer 41:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni gbogbo awọn enia, ti Iṣmaeli ti kó lọ ni igbekun lati Mispa, yi oju wọn, nwọn si yipada, nwọn si lọ sọdọ Johanani, ọmọ Karea.

Jer 41

Jer 41:6-18