Jer 38:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ijoye si tọ̀ Jeremiah wá, nwọn bi i lere: o si sọ fun wọn gẹgẹ bi gbogbo ọ̀rọ wọnyi ti ọba ti palaṣẹ fun u. Bẹ̃ni nwọn dakẹ nwọn si jọ̃rẹ̀; nitori ẹnikan kò gbọ́ ọ̀ran na.

Jer 38

Jer 38:20-28