Jer 38:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ki iwọ ki o wi fun wọn pe, Emi mu ẹ̀bẹ mi wá siwaju ọba, pe ki o má mu mi pada lọ si ile Jonatani, lati kú sibẹ.

Jer 38

Jer 38:24-28