Jer 36:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Elnatani ati Delaiah ati Gemariah bẹbẹ lọdọ ọba ki o máṣe fi iwe-kiká na joná, kò si fẹ igbọ́ ti wọn.

Jer 36

Jer 36:15-32