Jer 36:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sibẹ nwọn kò warìri, nwọn kò si fa aṣọ wọn ya, ani ọba, ati gbogbo awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀ ti o gbọ́ gbogbo ọ̀rọ wọnyi.

Jer 36

Jer 36:18-32