Jer 36:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni awọn ijoye sọ fun Baruku pe, Lọ, fi ara rẹ pamọ, iwọ ati Jeremiah; má si jẹ ki ẹnikan mọ̀ ibi ti ẹnyin wà.

Jer 36

Jer 36:16-28