Jer 33:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ wọnni, ati li akoko na, emi o jẹ ki Ẹka ododo ki o hu soke fun Dafidi; ẹniti yio si ṣe idajọ ati ododo ni ilẹ na.

Jer 33

Jer 33:6-17