Jer 33:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wò o, ọjọ mbọ, li Oluwa wi, ti emi o mu ohun rere na, ti emi ti leri fun ilẹ Israeli ati fun ile Juda, ṣẹ.

Jer 33

Jer 33:9-22