Jer 31:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa ti fi ara hàn fun mi lati okere pe, Nitõtọ emi fi ifẹni aiyeraiye fẹ ọ, nitorina ni emi ti ṣe pa ore-ọfẹ mọ fun ọ.

Jer 31

Jer 31:1-4