Jer 31:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa wi, Enia ti o sala lọwọ idà ri ore-ọfẹ li aginju, ani Israeli nigbati emi lọ lati mu u lọ si isimi rẹ̀.

Jer 31

Jer 31:1-7