Jer 27:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi niti opó mejeji, ati niti agbada nla, ati niti ipilẹṣẹ, ati niti ohun-èlo iyokù ti o kù ni ilu yi.

Jer 27

Jer 27:12-22