Jer 23:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li ẹnyin o wi, ẹnikini fun ẹnikeji, ati ẹnikan fun arakunrin rẹ̀, pe Kini idahùn Oluwa? ati kini ọ̀rọ Oluwa?

Jer 23

Jer 23:30-38