Jer 23:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati woli, ati alufa, ati awọn enia, ti yio wipe, Ọ̀rọ-wuwo Oluwa, emi o jẹ oluwa rẹ̀ ati ile rẹ̀ ni ìya.

Jer 23

Jer 23:27-37