Jẹ ki a gbọ́ igbe lati ilẹ wọn, nigbati iwọ o mu ẹgbẹ kan wá lojiji sori wọn: nitori nwọn ti wà ihò lati mu mi, nwọn si dẹ okùn fun ẹsẹ mi.