Jer 18:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Omi ojo-didì Lebanoni yio ha dá lati ma ṣàn lati apata oko? tabi odò ti o jina, ti o tutu, ti o nṣan, yio ha gbẹ bi?

Jer 18

Jer 18:7-15