Jer 18:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa wí, Ẹ sa bère ninu awọn orilẹ-ède, tani gbọ́ iru ohun wọnni: wundia Israeli ti ṣe ohun kan ti o buru jayi.

Jer 18

Jer 18:10-18