Jer 14:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Máṣe korira wa, nitori orukọ rẹ, máṣe gan itẹ́ ogo rẹ, ranti, ki o máṣe dà majẹmu ti o ba wa dá.

Jer 14

Jer 14:15-22